Jump to content

Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ abilà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ abilà
Zebras
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Ìjọba:
Ará:
Ẹgbẹ́:
Ìtò:
Ìdílé:
Ìbátan:
Subgenus:
Hippotigris and
Dolichohippus
Species

Equus zebra
Equus quagga
Equus grevyi
See here for subspecies.

Àwọn Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ abilà tabi awon Sebra (Zebra) je awon eranko iruketekete abinibi si Afrika to won se damo pelu awon ila dudu ati funfun ara wom. Awon ila yi se pato si okookan won. Won je eranko alawujo ti won se ri ni meji-meta tabi idaran titobi. Won yato si awon ibatan to sunmo won julo, awon esin ati ketekete, nito ripe won ko se e sin daada.